True
213;
The Jotter Keeper Nigeria

"Ẹ̀yin Tèmi, Ẹkáàárọ̀ nílé àti lókò. Èmi ni Ọmọ yín, Àbúrò yín, Ẹ̀gbọ́n yín àti Bàbá yín.

Abíọ́dún Ọmọ Ògúnsẹ́yẹ tí ẹ mọ̀ sí "Jọ́tà Kípà"

"Ẹkáàbọ̀ sórí ètò

'GBÀMGBÀ L’ÁṢÀ'."

"Lónìí, a ó máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ lórí ilẹ̀ wa Nàìjíríà. A ó máa mọ́nu bà àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹlẹ̀ nínú oṣù Fẹ́búárì. Bàbá kan ní Ìlú Ìbàdàn mọ́lọ pa ara rẹ̀ tó sálọ. Àwọn alábàgbé rẹ̀ rò pé otí ẹlẹ́rìndòdò ni ó ń mu lọ́jọ́ Ẹtì, ṣùgbọ́n májèlé ni ó gbé jẹ."

"Lẹ́yìn ìṣẹ́jú mẹ́rin-lélọ́gbọ̀n, wọ́n tún rí i pẹ̀lú aṣọ funfun tó sá gba yewu. Ǹjẹ́ ó pa ara rẹ̀ nítòótọ́? Báyìí la parí ètò náà sí, a ó máa tẹ̀síwájú ní ọ̀sẹ̀ tí ń bọ̀. Ẹ yáa ṣé o!"

1
views 4
0 share
Go to Abiodun's wall
What is TwoCents? ×